Smiley face

Se Bo Se Rorun Naa Nu-un Lati Da Gbogbo Oluko Ile Eko FUTO Duro?

Awon alase igbimo ile eko Federal University of Technology Owerri
(FUTO) ti da gbogbo oluko ile iwe naa duro pelu bi won se kuna ati pada si enu ise gege bi ase ijoba apapo.

Alukoro ile iwe naa, Ogbeni Chike Ezenwa lo se eleyii di mi mo.


Wayio, awon omo egbe ASUU eka ti FUTO ti salaye ko ye gbogbo aye wi pe awon ko ni pada si enu ise ayafi ti ijoba apapo ba teti si ohun ti awon n wi.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment