Oko Funke Akindele nigba kan ri, Kehinde Oloyede se ayeye ojo-ibi fun okan ninu awon iyawo re.
Lo ba fo fere lo so ri ero Facebook lati se afihan aworan orisiirisii pelu akara oyinbo ti won fi jo se ajoyo.
Leyin ohun gbogbo, ohun ti Kehinde Oloyede ko si abe awon aworan re re e :
"Happy birthday to a wonderful wife, I wishp you long life and prosperity in good health. Thank you for being there always, even when I go off track. Onisuru lo jogun ohun gbogbo.'
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment