Smiley face

Nigba Ti Boko Haram Yalu Ago Awon Omo Ologun Ni Ilu Maiduguri

Awon omo Boko Haram kolu ibuba awon omo ologun to wa ni ilu Maiduguri laaro putuputu ojo Aje to koja yii (2/12/13).
 
Bi o tile je wi pe awon omo Boko Haram bi merinlogun ni awon omo ologun fi bajinatu fo lori danu, sibesibe ado oloro ti awon omo Boko Haram ju ko sai ba n nnkan je koja ila.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment