Smiley face

Odaju Iya Ti Pa Omo Re Saye

Iru ese wo ni omo le se obi re to le mu ki won se  bi eru?
 
Ayafi odaju obi ti ko ni aanu ikunle abiamo. Arabirin
Maxwell ti fi ero ayoonu gbigbona jo omo re ti oruko re n je Blessing ni agbegbe Police College Barracks to wa ni Ikeja lojo Aje to koja yii. Awon agbofinro ti gbe Maxwell, bi o tile je wi pe olopa naa ni oko re.
 
Ibeere ti gbogbo eniyan n beere ni wi pe kini omo naa se to fi to si iru ijiya bayii. Maxwell nikan lo le so, awon ebi olopa nikan lo le salaye ko ye wa.
 
A ko ni mu ile ti ka oo
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment