Yaya Touré ti o je omo agbaboolu ile Ivory Coast ati Manchester City ni won ti gbe ami-eye 2013 BBC African
Footballer of the Year fun pelu ayo nla.
Lara awon ti won ba Yaya Touré du ami-eye naa ni Pierre-Emerick
Aubameyang, Victor Moses, John Mikel Obi ati Jonathan Pitroipa.
"Mo dupe lowo Olorun ati awon ololufe mi fun igbelaruge ati atileyin won fun mi" Yaya Touré
Home / Uncategories / Yaya Touré Lo Gba Ami-Eye BBC Agbaboolu Ile Adulawo To Pegede Ju Lo Fun Odun 2013
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment