Won ti kede ipapoda Oba Adebiyi Adesida, Deji ti Ilu Akure eni to lo ba awon baba-nla-baba re lorun ni aro ojo Aiku to koja yii (1/12/13).
Oba Adesida ku ni eni odun metalelogota(63), enikeni ko si le so pato iru iku to pa Oba Alade di akoko yii nitori awon oloye re ko lati menu ba orisii aisan to se baba.
Odun 2010 ni Oba Adesida gori aleefa leyin ti ijoba ro Oba Oluwadamilare Adesina to wa nipo loye.
Nibayii, won ti ti Oja Oba gege bi asa ibile titi won yoo fi je oba tuntun ni ilu Akure.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment