Smiley face

Omobirin Asewo To Ji Seeni Milionu Kan Naira To Fipamo Soju Ara Fun Ojo Meta

Tessy Emorvon omo odun merindinlogbon(26) kan lo ji seeni ale re kan ti oruko re n je Cosmos leyin igba ti won jo lajosepo tan ni ile itura.

Cosmos fi oro naa to awon olopa leti, sugbon awon olopa pada fi omobirin naa sile leyin ojo meji nigba ti won ko ri ohunkohun lowo re.

Seeni goolu ti owo re din die ni milionu kan naira ko je ki Cosmos gba wi pe Tessy ko lo ji seeni oun. Ojo ti awon olopa tu Tessy sile, ko ti de ile ti Cosmos tun fi Awon ASARS Ikeja mu un.

Owo awon SARS ni Tessy ti jewo to si mu seeni naa jade loju ara re (nnkan omobirin) nibi to fipamo si pelu owu to fi yi seeni naa to ti mu eje yo.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment