
Okan lara awon aso ti Beyoncé tun wo re nibi ayeye Grammy 2014 to waye lana ni Los Angeles to wa ni ilu Amerika. Akiyesi awon onwoye ni wi pe omobirin naa ti se atunse se ewa ara re, eleyii to se nipa adinku ara sisan. Won ni omobirin eni odun mijilelogbon (32) naa ti lepa ju ti tele lo, eleyii to tun bo mu ewa re jasi si ni gidi.
Nje eyin le wo iru aso oge ti Beyoncé wo yii?
Omobirin naa ko wo awotele rara, awon ododo ti won fi se ewa si ara aso naa kan bo awon ibi kan to lapera lasan ni.
0 comments:
Post a Comment