Smiley face

Omobirin Shakira Inu Jenifa Ti Pe Eni Odun Mejilelogbon (32)


Bi o tile je wi pe won ko se faaji naa ni alariwo sibesibe kosi ohun ti eniyan fe je tabi fe mu ti ko si lori tabili ti Ireti Osayemi Bakare gbe siwaju awon ore re ti won wa ba se ariya ojo ibi re to waye ni kopekope yii.
 
Lara awon osere to ba Ireti Osayemi lalejo nibi ariya ojo ibi odun mejilelogbon (32) re to se ni Iyabo Ojo, Doris Simeon, Bimbo Thomas, Sikiratu Sindodo ati awon ore re lorisiirisii.
 
 
A ki omo olojo ibi wi pe emi re yoo se opolopo odun laye. Amin








Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

1 comments: