Smiley face

Davido Ati Wizkid Ti Daran Awon Omo Ologun Naijeria


 
Awon Yoruba ti pari oro, won ni a wi fun ni ko to dani, agba ijakadi ni. Awon omo ologun ile Naijeria ti ko leta ranse si awon ilumooka ile Naijeria ti won feran lati maa wo aso awon omo ologun ni won ti kilo fun lati yee se bee mo.
Awon omo olorin ni aje iwabaje yii simo lori ju lo. Eleyii ti awon omo ologun se alaye won bi eni ti n fi aso iyi ati eye awon omo ologun ile yii se eleya nigboro.
Won ni pupo ninu awon omo olorin naa ni won maa n wo aso ologun sorun lode ere tabi ninu fidio orin won pelu igbo lowo won eleyii to n tabuku awon omo ologun.
 
Awon omo ologun Naijeria ko sai daruko Iyanya,Wizkid, Davido, Tekno Miles, ati Chidinma ninu leta ti won ko gege bi afoju sun won.
 
Won si tun fi kun un wi pe enikeni ti awon ba tun ri ninu won to woso ologun lai se wi pe won je omo ologun, iya o je irufe ni bee bi ole ni.



Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

3 comments:

  1. yusuff sheriffdeen21 January 2014 at 23:07

    Ema da awon olorin wonwon yen loun ikoja aaye ni ki won maa wo aso iyi aso eye awon omo ogun wa sere kaakiri,ko da oye ki ijoba wa gbe igbese lorie tori ti awon ologun ba se idajo fun ra won haa o ma lewu oo

    ReplyDelete
  2. Afoju di Lon damu awon omo olorin yen jare

    ReplyDelete