![]() |
Ola Abata ni i modo san... |
Se e ridan? Baba ati omo alara oge,
Peteru ati omo re, Cameron pelu aye oloba ni ilu Amerika.
Peter Okoye ati ebi re wa ni ilu Amerika lowo bayii nibi won ti je igbadun ninu ile won tuntun to wa ni ilu Atlanta.
![]() |
Cameron: Baba mi ni mo jo |
0 comments:
Post a Comment