
Okun ko le gungun-ungun ko maa nibi to ti se wa. Eniyan ko si ni bi omo niso sokoto ko wa lo jo kijipa. Eni bi ni laajo. Oserebirin ilu Ghana to je omo Naijeria, Yvonne Okoro ti salaye ibi to ti jogun aya re to ta galete bi isu ori ebe.
Oserebirin yii lo se afihan aworan iya re pelu akole to so wi pe
"Nibayii, oye ko ti ye yin ibi mo ti ri pofupoofu onigbameji nla ti mbe laya emi nikan"
0 comments:
Post a Comment