Smiley face

[Foto] Leyin Odun Keta Ti Joseph Yobo Se Igbeyawo : Ayeye Odun Ife Yobo Ati Adaeze Waye Pelu Idunnu Nla


Joseph Yobo se ayeye odun ife pelu ololufe re, Adaeze lati sami odun keta ti Eduamare ti fi adun si idile won ni ibere odun taa wayii. Aimoye ore, ojulumo, ebi ni won pejo ba awon ololufe meji yii yo ayo idunnu ni ile won to wa ni ilu Eko. E tesiwaju lati wo awon awonran to ku...







Iya Yobo Ati Iyawo Re
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment