Jude Okoye to je egbon awon omo meji ti won n korin, P-Square lo se afihan ibon re lori ero Instagram ni kopekope yii. Pataki ohun to mu Jude se iru nnkan bayii ko tile yeni, se o fi n sako ni tabi o fi n da eru ba awon ota (abi ka so wi pe awon ololufe re)?
E tesiwaju ....
![]() |
Mo lowo Mo nibon |
![]() |
Mo Lenu Bi ponponpon |
0 comments:
Post a Comment