Smiley face

Ile Itura Montana Magica Ni Chile Le Ku!



Gusu ilu Chile lo kale si ni Huilo. Bi o tile je wi pe ise owo awon omo eniyan ni agbekale ile itura Montana Magica, sibesibe onira pupo lati gbagbo pelu orisiirisii ara ti won fi ibugbe naa da.
Igbo (bush) yika ni, eleyii ti ko le je ki eniyan tete fura wi pe ibugbe kan ni bee si ni omi n da sile lati oke ile naa wa sile.

Yato si eleyii, won tun ni ogba eranko eleyii ti eranko igbo orisiirisii kun fofo fun iworan awon alejo ti won ba wa fokanbe pelu afefe alaafia ti n fe yee ni gbogbo agbegbe naa.


To ba ti ya ti e ba ti lo si ilu Chile, e gbiyanju ki e de ile itura
Montana Magica lati je kugu aye.










Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment