Smiley face

Omo Alao Akala Setan Lati Se Igbeyawo Pelu Omo Rasaq Okoya (Eleganza)



Lopin ose to koja yii, idile gomina Ipinle Oyo nigba kan ri, Adebayo Alao Akala se ayeye mo-mi-n-mo-o pelu Rasaq Okoya (Eleganza) ni ile baba iyawo to wa ni Eleganza Estate, Ajah ni ilu Eko.

Awon omo won mejeeji yii,
Olamiju Alao-Akala ati Hadiza Okoya ni won ni o seese ki won so won po gege bi toko-taya ki odun yii to pari.
 
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment