Sebi awon Yoruba loni inu eni ki i dun ka pa mora. Sola Kosoko to tun je okan lara omo Jide Kosoko se ayeye ojo ibi re laipe yii pelu ajoyo odun meje ti igbeyawo ti duro gbangban lai subu.
Faaji yii lo waye ni Ile ounje Chinese Restaurant to wa ni oju ona Mobolaji Bank Anthony, Ikeja, Lagos.
'Bi eniyan ba so wi pe suuru lo n mu igbeyawo duro, emi o so wi pe iro ni. Sugbon iriri mi fi ye mi wi pe ore ofe Oluwa nikan lo le mu igbeyawo ladun ko si pe. Mo dupe wi pe Olorun fun mi se. Mo wa laye, idunnu mi ko di ibanuje. Oko temi gan-angan ni Olorun fun mi' Sola Kosoko
0 comments:
Post a Comment