Smiley face

Jude Okoye Pelu Ibon Tuntun: Bajinatu Nla Sagila Lowo Egbon Awon P-square

Ibon ilewo kekere lo koko se afihan re pelu akole to wi pe :

'Ti e ba ta felefele, mo ni lowo.'

Nibayii, ibon sagila nla lomo Okoye tun fi n sako.

Orisiirisii oro idoti ni awon ololufe re ti beere si ni I so si pelu bi o se n se afihan ibon orisiirisii to ni lakata re.

Awon kan ni aigbon ni i da laamu, nigba ti awon mii so wi pe igberaga lasan ni i yo lenu.

Aimoye olorin ni mbe laye, okan ninu won lOsupa Akorede omo Okunola. Orin Baba Sulia lo so wi pe 'bo ba yo ko panu, ko ma sekun benbe tori paya gbege'.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment