
Awon Yoruba ni eni ba foju ana wo eegun, afaimo ki ebora ma gbe iru eni naa laso lo. Awon olorin Naija ti sun kuro nibi tana, joojumo ni won n peleke sii ninu ise orin to joju.
Nibayii, KCEE ti setan lati jumokorin pelu omo olorin olokiki ilu Amerika, Nicki Minaj. Gege bi a se gbo, owo bi milionu mejidinlaadorin (68M) owo naira ni won setan lati san gege bi owo ise fun omobirin olorin naa.
Ilu Amerika ni KCEE wa bayii pelu awon isomogbe re, ero won si ni lati pari ise orin ajumoko naa ki won to pada wale.
Bakan naa la tun gbo wi pe kii se Nicki Minaj nikan ni afojusun KCEE, oseese ko tun se afihan olorin olokiki nla mii ninu orin re ko to pada wa le.
Iru orin wo ni KCEE fe ko pelu Nicki Minaj na?
0 comments:
Post a Comment