Awon asewo ilu Brazil ti lo bere si ni i ko ede geesi bayii ni imura sile fun boolu agbaye ti yoo waye ninu osu kefa odun. Gege bi olori egbe awon asewo ilu Brazil se so, oni o se pataki ki awon omo asewo mo ede geesi so daada ni ona ati te awon onibara won tuntun lorun.
Akiyesi: ofin ilu Brazil fi aye gba ise asewo sise
0 comments:
Post a Comment