Ni agbegbe Iyana Oworosoki ni oko akero kan ti lana lonii. ijamba ina naa fa opolopo sunkeregbakere oko fun aimoye wakati. Bi o tile je wi pe awon eniyan tete dide fun iranlowo ati segun ina naa sibesibe opolopo eniyan lo fara pa ninu ijamba buruku naa.
Isele nla gba no eyii je oo
ReplyDelete