
Oserebirin Mistura Asunramu se ayeye ikomojade akobi omo re lopin ose to koja yii, aimoye awon eniyan lagbo amuludun ni won si peju sibe lati ba yo ayo omo tuntun. Lara awon eniyan to wa nibe ni omobirin alawada ti oruko re n je Princess, Saka wa nibe, Sola omo Kosoko naa ko si gbeyin nibi ayeye to waye ni ilu Eko naa.
0 comments:
Post a Comment