Smiley face

Pastor Chris Oyakhilome Fi Apeere Rere Lele


 
Adari ijo Christ Embassy, Alufa Chris Oyakhilome ti fi gbongan nla kan ta Ifafiti Ambrose Alli to wa ni Ekpoma lore. Eleyii ni won se nibi ayeye to waye ninu gbongan naa nibi ti Pastor Chris ti ko gbogbo kokoro gbongan nla naa le Gomina Adams Oshiomhole ti Ipinle Edo lowo.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment