Smiley face

Oko Ofurufu Awon Omo Ogun Ile Amerika Jabo Ni Ilu Oba

Iroyin to n de ba eti igbo wa ni gbigbona fi ye wa wi pe oko ofurufu ti ile Amerika kan ti jabo ni ilu UK ni apa arewa-ilaoorun ilu naa.

Awon eniyan bi merin ti won mbe ninu oko naa ni awon agbofinro so wi pe won ti ba isele naa lo.

E kunrere iroyin n bo laipe.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment