
Awon Yoruba ni ola abata ni i modo san, ola baba omo ni mu omo yan fanda. Bi Jamil ko ba jaye, talo tun fe jaye? Jamil Abubakar ni yii, omo I.G oga oloapa patapata, Mohammed Abubakar. Oke okun ni omo naa ti ka iwe a si ri gbo wi pe ise awako ofurufu lo n se ni ile ise Elite Airwings. Inu ola ni omokunrin naa ti n jaye oloba nigba to n se afihan awon dukiya re.
Jamil pelu awon olopa to n so tosan toru
Awon ago Jamil to fi n logba
Die lara awon oko bogini ti Jamil fi n jaye oloba
![]() |
Jamil ati baba re |
0 comments:
Post a Comment