Smiley face

Awon Senato Alagbara Mokanla (11) Ti Fo Lati Inu Egbe PDP Bo Sinu Egbe APC



Iroyin tuntun mii tun seyo loju orun, eleyii to n so nipa awon Senato bi mokanla ti won je ti egbe PDP se pinnu lati maa ba egbe APC lo lonii. Osan oni yiii ni won yoo te pepe alaye ati ero won si iwaju ile.


 
Awon Senato naa ni:

Senator Bukola Saraki-Kwara Central.
Senator Umaru Dahiru-Sokoto South
Senator Magnus Ngei Abe -Rivers South-East
Senator Wilson Asinobi Ake-Rivers West
Sen. Bindawa Muhammed Jibrilla-Adamawa North
Sen. Mohammed Danjuma Goje-Gombe central
Sen. Aisha Jummai Alhassan-Taraba North
Sen. Mohammed Ali Ndume-Borno South
Senator Mohammed Shaba Lafiaji-Kwara North
Sen. Abdulahi Adamu-Nasarawa West
Senator Ibrahim Abdullahi Gobir-Sokoto East

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment