Nnkan bi opin odun to koja ni Karen Igho Kede lori ero twitter re wi pe oun ni aisan jejere ti a mo si cancer. Awon kan ni boya ere lasan lo fi n se, sugbon oro naa ki i sere rara. Omobirin naa ti wa ni ilu Oba lowo bayii nibi to ti n gba itoju lowo.
Ki Oba Oluwa da alaafia pada si lara.
0 comments:
Post a Comment