Smiley face

P-square Setan Lati So Yigi Igbeyawo Won Lojo Kan Soso

Anita ati Lola
 
Peter ati Paul Okoye (P-square) setan
lati so yigi  pelu awon ololufe won mejeeji ninu osu kerin odun taa wa yii. Bi o tile je wi pe won ko ti kede ojo kan pato ati ibi ti igbeyawo naa yoo ti waye, sugbon o jo bi eni wi pe ilu Dubai ni won fe fi ariya  naa si pelu bi a se gbo.
 
 


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment