
Leyin bi ose kan seyin ti Jude Okoye to je egbon awon omo meji olorin, P-square to tun un sise gege bi olootu ati oludari orin awon aburo re lo ti toro aforijin latari awon aworan re pelu ibon oloro ti fi n han aye.
Gege bi oro re, oni oun ki i se onijagidijagan eniyan, ati wi awon aworan naa je okan lara aworan fidio orin kan ti awon ya lowo ni.
Sebi awon Yooba naa ni won wi pe ere la n fi omo ayo se. Eniyan ki i si mo iyan ewura gun ko ma ni koko. Jude ni ke e jebure awo olugbebe.
0 comments:
Post a Comment