Smiley face

A Se Pasuma Le Pade Se Igbeyawo?

Ti ẹ ba gbọ wi pe Baa-Wasi se igbeyawo lọwọ yii, a jẹ wi pe eyi to se ninu sinima ti Jaiye Kuti ni. Ninu sinima ti won pe akọle rẹ ni ‘Jaiyeola Ni Mo N Je’ lati ri Adebayo Salami, Yinka Quadri, Henrietta Kosoko, Faithia Balogun, Femi Adebayo, Ojo Arowosafe ati Yomi Gold.

E ku oju lọna!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment