Smiley face

Asọ Ti Rihanna Wọ Lana Baadi Gan


Rihanna loni ko si ohun ti oun ko le fi ara aso oge da, lo ba ku pinnu lati lo si bi isafihan aso oge ti won pe ni Paris Fashion Week lana lai wo awotẹlẹ ti o le bo aya rẹ. Won ni ara oge tuntun ni. Njẹ a le pe iru asọ bayii gẹgẹ bii oge tuntun bi?



Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment