Smiley face

Iru Ẹbun Wo Ni Samuel Eto'o Fun Davido?



Davido ti dupe lọwọ agbaọjẹ agbabọọlu ile Adulawo, Samuel Eto'o  pẹlu ago Rolex  alarambara olomi goolu to fi ta lorẹ. Sebi ẹni ba dupe ore ana, dandan ni ko ri òmíìràn gba. 

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment