Smiley face

Awon Dokita Ri Ehin Ninu Ọpọlọ Ọmọ Osu Merin

Awọn onimọ isegun ilu Ọba ti se afihan iriri kayeefi ti won ri pẹlu bi won se ba ehín ninu ọpọlọ omo osu merin. Omo osu merin yii ni won se akiyesi wi pe ori rẹ n sare tobi ju bo ti yẹ lo ni won ba ya aworan inu ori omo naa. Aworan naa ba se afihan ehin agbọ̀n ìsàlẹ̀ ninu ọpọlọ. Won ti se isẹ abẹ fun omo yii, won si yọ ehin naa jade. Sugbọn ọmọ naa ko ti gbadun tan titi di akoko yii.  Ẹ tun le ka si wa ju NIBI

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment