Smiley face

Desmond Elliot Ti Kuro Lomo Agbekorun Roko

 
Eni odun ba ba laye ko sope, aimoye lerupe ti bo mole. Oserekunrin omo ile Naijeria, Desmond Elliot pe eni odun merindinlogoji lana ojo kerin osu keji odun (4th February 2014) lo ba pe gbogbo aye lati ba fi ope fun Oluwa oba.


Victoria Island to wa ni ilu Eko ni apeje naa ti waye, awon osere bi Rukky Sanda, Rita Dominic, Emem Isong, Alex Ekubo, Majid Michel, IK Ogbonna ati Uru Eke wa nibi ayeye naa.

Igba odun, odun kan!


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment