Ogbeni Royston Grimstead ti fi ibinu fi aja re se sadaka leyin ti aja re ti je abala kan lara moto re eleyii to ra ni nnkan bi egberun lona ogorin owo poun (£80,000).
Gege bi oro re, oni oun pada dele ni oun ba ri ti aja ti je moto oun sakasaka. O ni oun to jo oun loju ni wi pe aja naa ko se ohun to jo mo bee ri.
Gege bi akiyesi, owo ti yoo tun moto naa se yoo fe to nnkan bi egberun meta owo poun ti ilu UK (£3000).

0 comments:
Post a Comment