Smiley face

Oro Ti Omo Odun Meta So Sile Ki Iku To Mu Lo

Ibere ogun la mo, ko si eni ti i mo opin ogun. Oro ti omo kekere, omo odun meta ilu Syria so gbeyin ti di arojinle fun awon ologbon aye pata.
 
"Gbogbo re ni maa so fun Eledumare".
 
Rogbodiyan ti n sele ni ilu Syria ti mu aimoye emi lo, aimoye awon eniyan ni ko si ni ile lori mo. Eleyii si waye latari ija ogun abele ti n sele ni ilu naa eleyii ti opolopo si n pariwo olori ilu Syria,
Bashar al-Assad gege bi ika eniyan ti n fi ara ni omoniyan.
 
Omo odun meta yii naa wa lara awon to se agbako iku, gbolohun to so keyin si ti di iberu fun gbogbo awon alagbara aye pata.
 
"Gbogbo re ni maa so fun Eledumare"
 
Sebi ile aye o le, omo eniyan lo so aye dogun. Eniyan lo si n seku pa eniyan.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment