Smiley face

Awon Ota Fasola Ti Dide Ogun

Awon omo egbe PDP ti bu enu ate lu Gomina Ipinle Eko, Amofin Babatunde Raji Fashola pelu bo se fo ogiri ti won fi dabu ona si meji. Awon omo egbe PDP so wi pe gomina ko fi apeere rere lele rara pelu iwa to wu naa. Won ni Gomina Fasola ti jebi irinna oju popo, o si ye ki awon osise LASTMA san kondo mo gomina leyin pelu iru iwa bi eleyii.

Nje a le gba wi pe ododo oro ni awon omo egbe PDP so tabi awawi lasan ni?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment