Smiley face

E Sora! Satellite Maa Jabo Loju Orun Lonii (16/02/14)


Awon onimo sayensi ti kede wi pe Satellite ti ilu Russia ti mbe loju orun seese ko jabo si orile aye loni (16/2/14). Bi o tile je wi pe inu okun lo ye ko jabo si, sugbon won salaye wi pe ipo ti satellite naa wa ko dara to eleyii to seese ki ajaku re fon si orile aye eleyii ti enikeni ko si le so ibi ti ajaku re yoo fon da.
Fun idi eyi, won ni kede "Ifura Loogun Agba Fun Gbogbo Agbaye". Awon onimo yii ro awon eniyan lati maa sora ki won si maa wo oju orun latari ijamba to le sele ti satellite naa ba jabo.
Odun 1980 lagbo wi pe won gbe satellite naa si oju orun eleyii to si ti pari ise bayii.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment