Olayemi oro mi ko po rara, alaye mi ko si gun bi eti so. Eniyan to ti ku ni tie tan. Eniyan ti ko si laye mo ni ko ba won jeeyan mo laye. Mo ba Yinka Ayefele dupe, mo si ba ayo fun didasi ti oba Oluwa da si funfun gbogbo wa. Mo gbadura Alaafia, ayo, idunnu ati emi gigun fun omo Ayefele. Amin.
Igba odun, odun kan ni.
Happy Birthday!
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment