Smiley face

Magasiini Forbes Ti Kede Awon Alagbara Mewaa Lati Ile Afirika



Iwe iroyin Forbes Magasiini agbaye ti kede awon eniyan alagbara Mewaa ti won je okunrin lati ile Afirika. Sebi ti Yoruba ba ni ajurawa lo bi tijakadi ko. Ogbon ju agbara lo, olopolo loga alagidi.

Awon alagbara naa ni yii;


1. Simdul Shagaya: Oludasile Konga.com ati DealDey.com

2. Chinedu Echeruo: Oludasile Hopstop.com ati Tripology.com


3. Kola Karim, (omo Nigeria), Olori ati alakoso Shoreline Energy International.


4. January Makamba, Tanzania, Igbakeji minisita fun ibanisoro, sayensi ati imo ero bakan naa lo tun je okan lara awon omo igbimo ilu naa.


5. Ashish Thakkar, Uganda, Oludasile Mara Group, Mara Foundation ati Mara Online


6. Mamadou Toure, Cameroon, Oludasile ati iludari Africa 2.0


7. Amadou Mahtar Ba, Senegal, Oludasile ati oludari African Media Initiative


8. Ben Magara, Zimbabwe, Oga agba ati olusakoso fun ile ise Lonmin


9. Komla Dumor, Ghana, Atokun eto "Focus On Africa" lori afefe ati oniroyin BBC World News' European morning segment


10. Mohammed Dewji, Tanzania, oga agba ati olori ile ise Mohammed Enterprises Tanzania Limited
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment