Smiley face

Justin Bieber Mu Die Ninu Oyan Omobirin Alajota Ni Los Angeles

 

Won ni Justin Bieber fe gbori won ile orin Los Angeles ti ilu Amerika ni awon ololufe omo odun mokandinlogun(19) naa ba seto faaji ranpe fun un. Won lo fi owo gba awon omo onijo alajota pelu eru aya won to ta bokua bi isu Abuja wa soju agbo.

Oyan awon omoge yii wo Justin Bieber loju ni oun ati ore re, Khalil ba pinnu lati to die wo nibe.


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment