Smiley face

Atiku Abubakar Naa Ti Fi Egbe PDP Sile Bo Sinu Egbe APC




Igbakeji Aare Naijeria nigba kan ri, Atiku Abubakar ti pada kede fifi egbe PDP sile bo sinu egbe APC.

Gege bi oro re eleyii to jade lonii se so. Alh Atiku Abubakar ti setan lati ba egbe Tinubu lo. Agbaoje oloselu yii lati Ipinle Adamawa si ti ro gbogbo awon omo leyin re ninu oselu lati fi oruko sile gege bi omo egbe APC nikete ti eto iforuko sile ba ti bere.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment