Smiley face

Asọ Igbeyawo Onihoho Lo Gbode


Bi o tile je wi pe gbogbo eniyan ni won fe wo aso ara oge lojo igbeyawo won, sebi ki eniyan wo aso onihoho ni? Sugbon sa, bo ba ti wuni laa se imọle eni, eni o ba fẹ le fi itan ẹlẹdẹ jẹ saari. Ka tile gbe awada sẹgbẹ kan, njẹ ẹyin le wọ iru asọ bayii lọjọ igbeyawo yin tabi ki ẹ gba ki iyawo yin wọ sọrun?


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment