Smiley face

Genevieve Nneji Ti Ba Mikel Obi Lo

 
Olayemi, ohun ti ko kan mi emi ki i da si i rara. Sugbon niwon igba ti Genevieve Nneji ti ba Mikel Obi lo bayii ko si ohun to kan eniboodi nibe. Ilu South Africa ni won ti ri Oserebirin Genevieve to wonu baalu pelu Mikel Obi. Moto otooto ni awon mejeeji gbe wa si papako ofurufu naa. Oko Bently ni Genevieve gbe wa, nigba ti Mikel gun orisii moto kan ti n je Aston Martin.


Baalu ti awon mejeeji wo kii se baalu gbogbo ero rara, enikeni ko si le so ibi awon mejeeji jo n lo. 

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment