Beyonce kọ lara orin rẹ tuntun to pe ni XO nibi ami eye BRIT Awards to waye lana ode yii ni ilu London.
Gbongan nla ti O2 arena kun fun ariwo nla nigba ti agbaojẹ olorin ẹni odun mejilelogbon (32) lati ilu Amerika ja gbogbo eniyan laya pẹlu bo se gun ori itage orin pelu asọ oge àrà onina yinginyingin ti awon eniyan se apejuwe rẹ gẹgẹ bi àwò-dami-ẹnu.
Beyonce pada sinu baalu rẹ nikete to korin tan lai fi akoko sofo.
Beyonce boju weyn lati dagbere fun ilu London
Beyonce ninu baalu re saaju ki ọkọ̀ naa to gberá sọ́
0 comments:
Post a Comment