Smiley face

Oniroyin CNN Fi Pata Ya Fọtọ Ni Ilu London

 Oniroyin ti n jábọ̀ nipa Asọ Oge ni Myleene Klass lori telifisan agbaye CNN. Oun naa wa nibi ami ẹ̀yẹ BRIT Awards to wa lana ni ilu London. Myleene Klass wo asọ alawo fèéfèé to ni asẹ́, eleyii to n se afihan awọtẹlẹ dudu to wọ sinu. Won ni ara oge tuntun ni ki obirin wọ asọ ki gbogbo awọtẹlẹ si di ohun ti gbogbo eniyan yoo maa ri nita. Inu Myleene Klass dun yato lana nitori gbogbo eniyan ni won fẹ ba ya fọtọ latari asọ rẹ.


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment