Awon ọmọ Boko Haram tun ti pada fi emi awon eniyan bi metadinlaadota (47) sofo lana ode yii ni agbegbe Bama to wa ni Ijọba Ibilẹ Bama to wa ni Ipinle Borno.
Se bi yoo se maa ri lo niyi titi ti awon Boko Haram yoo fi pa awon eniyan ti won gbe ni Ipinle Borno tan patapata?
0 comments:
Post a Comment