Won ti ile ounjẹ igbalode Pizza Huts to wa ni West Virginia latari bi ọkan lara awon osisẹ ile ounjẹ naa se n tọ sinu ibi won ti n fọ abọ ti awon eniyan fi n jẹun to wa ni yara ile idana. Camera ti won so moke lo tu asiri okunrin naa, awon alasẹ si ti pase ki won ti ile ounjẹ naa pa bayii.Ẹ le wo fidio nnaa [NIBI]
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment