Won ni ti òpin ayé ba ti de orisiirisii la o maa ri. Omobirin onísẹ́ nàbì (asẹ́wó) yii to pe oruko ara rẹ ni Blondie Bennett ti bẹ awon dokita lọ́wẹ̀ lati ba ko ọpọlọ rẹ̀ kúrò ninu ori rẹ̀. Oni o wu oun ki oun dabi bèbí alainilaakaye rara. Omobirin eni odun mejidinlogoji lati ilu Califonia ẹni to ti fi ìgbà kan ri na owó tótó bi milionu meje owo naira (N7M) lati fọn ọmú àyà rẹ jade so wi pe iru igbe aye to wu oun ni lati dàbi bàbí, ko maa si iyè tabi ohun ti a le pa laakaye ni ori oun.
[Isẹ èsù lèyí jọ loju te mi o]
0 comments:
Post a Comment