Karen Igbho ti pada wálé lati ilu Ọba nibi to ti n gba itọju latari aisan jẹjẹrẹ. Lati ọdun to kọja ni omobirin naa ti wa ni ilu UK, a dupẹ wi pe ara rẹ ti ya bayii.
Ewu ina kii pa awodi, awodi o ku ewu!
Reviewed by Olayemi Oniroyin
on
2/19/2014 11:25:00 pm
Rating: 5
0 comments:
Post a Comment